Zidane ti o je coach real madrid ni o siwaju awon mejila ti won dije fun FIFA men’s coach of the year award. Awon Oludije toku ni Antonio Conte ti o soju egbe agbaboolu Chelsea ti won si gba ife premier league, Jose Mourinho ti o je asoju Manchester United ti o gba europa league ati Massimiliano Allegri ti Juventus.
E TUN KA: D’banj Kede Ojo Agbekale Awo Orin E “KingDonCome”
Zidane ti gbadun odun ti o fi se asoju real madrid ti won gba European Cup ti o so won di egbe agbaboolu akoko lati gba leraler. Labe Zidane na, Real madrid gba la liga ni odun ti won gba European cup ti o tun so won di champions of Spain and Europe lati 1958. Zidane ti gba ife meje (seven trophies) lati igba ti o ti gba ise lowo Rafael Benitez ni january 2016 ti won si gba UEFA Super Cup ati Spanish Super Cup ni osu yi.
Awon Coach ti won yan fun FIFA’s coach of the year award ni:
Massimiliano Allegri (Juventus/ITA),
Carlo Ancelotti (Bayern Munich/GER),
Antonio Conte (Chelsea/ENG),
Luis Enrique (Barcelona/ESP),
Pep Guardiola (Manchester City/ENG),
Leonardo Jardim (Monaco/FRA),
Joachim Loew (Germany),
Jose Mourinho (Manchester United/ENG),
Mauricio Pochettino (Tottenham Hotspur/ENG),
Diego Simeone (Atletico Madrid/ESP), Tite (Brazil),
Zinedine Zidane (Real Madrid/ESP)