Skip to content

Yinka Quadri Se Ajoyo Ojo Ibi Odun Meji Din L’ogota Re L’Ona Ara

Agba Osere Nollywood, Yinka Quadri ti se afihan awon aworan ara re lati fi se ajoyo ojo ibi Odun Meji  Din Logota Re. Osere to dangiajia yi fi han wa wipe number lasan ni ojo ori je ninu awon aworan naa.

E TUN LE KA:OSERE ENIOLA BADMUS SE OJO IBI OGOJI ODUN

yinka-quadri-bday-orisun

Ise Osere Ogbeni Yinka quadri bere ni 1976 nigbati Oun ati Ogbeni Taiwo Olayinka pelu awon ore kan padiapopo lati da egbe osere Afopina Theatre Group sile leyin ti o fi ile iwe sile. Ogbeni Yinka Quadri ti se ere bi Aadorun (90) ere agbelewo Yoruba lati igba ti o ti bere sini show lori ere Agbodorogun.

yinka-quadri-orisun  yinka-quadri-orisun