Skip to content

Won Ti Mu Ojo ‘Keedogbon Gege Bi Ojo Ibo-Ifiropo Ni Ilu Eko

Ajo Ti O N Boju To Oro Ibo Ni Nigeria iyen The Independent National Electoral Commission (INEC) so lojo Aje wipe Ibo-ifiropo si aga ile igbimo asofin ni agbegbe Eti-osa 1 (Eti-Osa Consistuency 1) ni ilu eko yoo waye ni ojo keedogbon osu kesan Odun ti a wa yii.

Ogbeni Sam Olumekun ti o je Komisona Ibo ni awon agbegbe; Resident Electoral Commissioner (REC) ni ilu eko kede Ojo naa ni ipade awon agbaagba  awon adari egbe kookan ni o peju-pese si olu ileese Ajo naa.

Ajo NAN (News Agency of Nigeria) so wipe Ibo-ifiropo naa maa waye lati fi ropo Ogbeni Kazeem Alimi ti o s’alaisi ni ojo ikejidinlogun osu keje odun yii.

Leyin ti o se Ojo ibi ti o pe omo aadota odun ni o gbekuruje lowo ebora ni Ile-iwosan ti ileewe ijoba ilu eko (Lagos state University Teaching Hospital) pelu aisan ranpe.

Akapo Isakoso Ajo INEC ni Ilu Eko, Dokita Mudashiru Mustapha so tele ni ojo ‘kokanla osu kejo wipe osu ‘kerindinlogun odun yii ni won yoo di ibo naa. Ni ojo naa lohun, o so wipe awon ko tii pinnu; won si n duro de ase lati owo Adari Ajo INEC patapata.

Ijoba Ile Wa Ti Ko Iroyin Nipa Iyapa Ninu Isejoba Buhari

The Inter-Party Advisory Council (IPAC), after Mustapha’s disclosure, urged the electoral body to shift the proposed date for the bye-election by two weeks.

The group appealed to INEC to consider Sept 30, stressing that they just finished a local government election in the state.

Ajo ti o n bojuto awon egbe oselu elekanka ni ile wa Inter-Party Advisory Council (IPAC) ro awon INEC wipe ki won sun ojo ti won ti mu naa ti o je September 30 si iwaju pelu ose meji. Egbe naa rawo ebe si INEC. Won so wipe isunsiwaju naa yoo fun awon egbe naa laaye lati ko awon eniyan jo ati lati gbaradi fun Ibo naa t’o nbo.

Olumekun, the new Lagos REC, told the stakeholders at his maiden meeting with them that Sept. 30 had been approved by the INEC national headquarters after considering the recommendations by party leaders.

Olumekun ti a soro re loke t’o je Komisona ti ilu eko so fun awon asoju egbe ti o wa ni ibi ipade naa wipe, September 30 ti awon yan yii wa lati enu awon agbaagba ti o di INEC mu bi o se jeyo ninu erongba awon Adari egbe kookan.

EWO BI ATABATUBU ATI OLORI SE N LU GANGAN

Gege bi oro re, O so ni ede geesi wipe:

”This meeting is an opportunity for me formally introduce myself to stakeholders in the state and discuss the modalities for the forthcoming Eti-Osa I bye-election that has been slated for Sept 30.

”Time table has been drawn and we have given them out to the parties. The commission will monitor these activities.

”INEC is taking the management of elections to higher level. Since 2011, we have progressively improved on our performance.”

”We have designed new tools which we are going to work with to conduct a very fair, credible, peaceful and conclusive election,” he said.

Olumekun urged political parties to conduct their activities peacefully and partner with the commission in the areas of voter registration and education.

”Voters’ education is very key to the growth of democracy and INEC alone cannot educate and mobilise the citizens to perform their civic responsibilities.”

”We have about 1.4 million Permanent Voter Cards that are yet to be collected. We are appealing to political parties to help mobilise and encourage the people in this regard, and be part of the voter registration,” Olumekun said.

Reading out the timetable for the forthcoming bye-election, Mr Oladosu Balogun, Head of Department, Electoral Operations, INEC-Lagos, said the conduct of primaries by political parties was from Aug. 26 to Sept. 5.

”Forms should be collected from Abuja and the last day for submission of Forms CF001, CF002 and nomination form at INEC headquarters in Abuja is Sept. 7, while the last day for the publication of list of nominated candidates will be Sept. 14.”

”Sept. 23 is for the submission of names and addresses of party agents to electoral officers. Campaigns have started and the last day for campaigns is on Sept.28. Election will then take place on Sept. 30, ” Balogun said.

IJOBA APAPO PE FRIDAY ATI MONDAY NI ISINMI FUN ODUN ILEYA

Asoju egbe All Progressive Congress (APC) ti ipinle eko, Ogbeni Charles Odugbesi, gba won ni imoran wipe ki gbigba ati didapada iwe-igbaniwole sele ni ilu eko dipo ilu Abuja ki o ma baa gba akoko tabi fa inawo nla.

Also Mr Shola Omolola, Lagos State Chairman, Action Alliance (AA) said that the timing for the primaries was short and appealed for an extension of the date to allow political parties conduct their primaries adequately.

Mr Kola Ajayi, State Chairman, IPAC, urged the commission to make the form available online.

Beeni Ogbeni Shola Omolola ti o je alaga fun egbe Action Alliance (AA) ni ilu eko so wipe akoko ti a fi sile fun idibo abele ti kuru ju; o si bebe fun isunsiwaju ojo ibo naa ki aye le wa fun awon egbeegbe lati di ibo abele ti won.

Ogbeni Kola Ajayi ti o je alaga ipinle IPAC ro awon ajo wipe ki won jeki iwe-igbaniwole naa wa lori ero-ayelujara.

E LE WO FIDIO MIRAN LOKE PATAPATA PELU BOTIINI PLAY:

E TUN LE WO: