Won Ma Ti Fe Ti Gbogbo Ile-Eko Pa Ni Osun
Ijoba Ipinle Osun ti fun awon ile-eko to le ni Irinwo ni ose meji lati lo fi oruko sile ni ni ajo eko ti ipinle na ki won si ko gbogbo awon nkan ti o m fi han pe won ni eto lati da-ni ile-eko dani tabi ki won ni wahala pelu ijoba ki won si ti ile-eko na pa.
Ogbeni Festus Olajide to je akowe fun ajo eto eko Ipinle Osun lo fi Ipe ati ikilo na ranse si awon ti o da-ni ile-eko lati odo awon oniroyin apapo eka ti Osogbo.
Ajo eto eko na ti ti se iwadi si won si ri wipe ile-iwe ti ko ti ko forukosile dada ni odun 2016 n lo bi irinwo ati ogorin-le
ikede pataki si ti jade, won si fi to won leti pe won gbodo fi oruko sile larin ose meji aijebe! won ma ti ile-eko won pa patapata.