Skip to content

Wahala N Sele Ni Ilu Edo O- Pally Iriase Lo So Bee

Wahala N Sele Ni Ilu Edo O- Pally Iriase Lo So Bee

Asoju-sofin to soju apa ilaoorun ati iwo oorun ‘Etsako Owan’ ati ijoba ibile Akoko-Edo, Ogbeni Pally Iriase ti ke si ijoba apapo lati kede “ilu o fararo” ni ipinle Edo latari ipaniyan, ijinigbe ati ifipabanilopo to n gbile lojojumo ni ipinle naa.

IROYIN MIRAN: Otito Nipa Iku Ti O Pa Ogbeni Pasito Ajidara Osere Ori Itage

O so wipe, emi awon eniyan ibi ti a daruko saaju, wa ninu ewu nitori awon iwa odaran yi n di alafia ilu oun lowo.

O fi kun wipe, bi ago Olopa ati bareke-Ologun ti wa ni awon agbegbe yii to; sibe,won ko ri nnkan se si oro awon koloransi eda yii.

Lakotan, o ro ijoba lelekannka ati awon eso abo ile nigeria lati tete wa nkan se si iwa odaran to n gbile ni ipinle Edo; nitori emi ati dukia awon eniyan.

E LE WO FIDIO YII: