Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so
First Lady Mavin iyen Tiwa Savage soro nibi iforoworo kan pelu awon oniroyin nipa igbesi aye e ati awon nkakan ti awon eyan ko mo nipa e.
E tun le ka: Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun
Gbaju-gbaja olorin naa ti won beere lowo e wipe kini awon nkan meta ti awon ololufe e ko mo nipa e; ti o si dahun ti o so wipe oun ko feran lati maa wo bata giga, o feran bata ti o pelebe, ounje ti o feran ju ni bread o tun tesiwaju lati so wipe oun feran lati maa so nitori ara maa n tu oun.
Ti e ba ranti wipe laipe yii ni oga ile-ise orin ti o n ba sise Don Jazzy gbe aworan Tiwa si ori ero ayelujara ti o si koo si abe re wipe;
”Person no go know say your mess fit kill person. #SavageMess.