Skip to content

Ti Mo Pada Ba Ra Arsenal, Maa Le Wenger Da Nu- Aliko Dangote

Aliko dangote ti o je okan ninu awon olola julo ni Africa ti so ninu aforowero pelu Bloomberg wipe nkan akoko ti oun ma se ti oun ba ra egbe agbaboou Arsenal ni wipe oun ma le adari egbe na Arsene Wenger danu. Aliko Dangote so wipe oun ma gbero lati ra egbe agbaboolu na ti  $11 billion oil refinery ti oun ko si ilu eko (lagos) ba pari.

The first thing I would change is the coach. He has done a good job, but someone else should also try his luck.”

E TUN LE KA: Mo Pelu Idagbasoke Wizkid, Bo fe Bo Ko- Samklef

Arsene Wenger se sign contrac odun meji pelu egbe agbaboolu arsenal ni May odun 2017. Odun 1996 ni won gbe si ori oye adari egbe agbaboolu na ti o si ti gba ife premier league Meta (3) ati Ife Fa cup meje (7)