Anobi Ibrahim ti awon elesin keji mo si Abraham je okan ninu awon anobi ti olorun yo nu si ti o si fi ara re han si. Opo eniyan o mo pe igbese aiye anobi ibrahim je nkan eko fun awa omo eniyan atiwipe opo eniyan musulumi ati christian o mo nipa itan igbese aiye Anobi nla yii…
E TUN LE KA: Eekan ni Hajj Lilo Je Oranyan fun gbogbo Musulumi
Lori eto Ojumo Ire pelu atokun wa Owo Adua, alejo won yannana Itan igbese aiye anobi ibrahim…