Skip to content

TAANI ANOBI IBRAHIM, IRU EEYAN WO LO JE?

Anobi Ibrahim ti awon elesin keji mo si Abraham je okan ninu awon anobi ti olorun yo nu si ti o si fi ara re han si. Opo eniyan o mo pe igbese aiye anobi ibrahim je nkan eko fun awa omo eniyan atiwipe opo eniyan musulumi ati christian o mo nipa itan igbese aiye Anobi nla yii…

E TUN LE KA: Eekan ni Hajj Lilo Je Oranyan fun gbogbo Musulumi

Lori eto Ojumo Ire pelu atokun wa Owo Adua, alejo won yannana Itan igbese aiye anobi ibrahim…