Skip to content

Super Eagles Fi di Remi Ni CHAN Qualifier

Egbe agba boolu Super Eagles  fi di remi nibi ayeye boolu 2018 African Nations Championship (CHAN) qualifier ti o waye ni ojo aiku, August 13 ti won ti padanu 1-0 si agba boolu orile ede Republic of Rwanda.

Awon super eagles wa ni 0-0 tele ki awon republic of rwanda to gba penalty ni 90th moinute ti agbaboolu Mama Seibou gba si inu awon super eagles ti o fi fun won ni 1-0 ni first half.

E TUN LE KA:

Nigeria ti yege lee meji ni ibi idije Chan ti won gbe ipo keta (third) bi ilu south africa ni 2014 ti won si fi idi remi ni first round ni rwanda 2016. Egbe agbaboolu ti o ba yege ni ibi idije ese mejeeji lo ma lo dije ni ibi idije 2018 CHAN ni Kenya