Sultan ilu Sokoto ati Alaga Nigerian Supreme Council for Islamic Affairs, Alhaji Sa’ad Abubakar,ti kede pe ojo jimoh September 1, 2017 ni ojo Ileya. Ikede yi wa lati owo Prof. Sambo Junaidu, alaga Advisory Committee lori esin si sokoto sultanate council…“The advisory committee in conjunction with the National Committee on Moon Sighting received various reports on moon sighting across the country confirming the sighting of new moon of Zulhijja on Tuesday Aug. 22, 2017,’’
Ikede yi tumo si wipe ojo jimoh Friday September 1st ni ojo ileya. Sultan ki gbogbo musulumi ti o wan i Nigeria ku odun pe ito allah, aabo ati ibukun ma wa pelu gbogbo won. O so siwaju si wipe ki gbogbo musulumi gbe ni ayo ati Alafia, ki won si maa ki irun wakati marun won deede, ki won si gba adura irepo fun orileede Nigeria.