Skip to content

SOLA KOSOKO,SAIDI BALOGUN,OMOTOLA JAJALDE LORI SET ERE SHADOW PARTIES

Omotola jalade ekeinde ti bere ise lori ere agbelewo tuntun ti o pe  i “Shadow Parties” ti awon osere jankan jankan bi Saidi Balogun, Sola Kosoko, Rotimi Salami, Busola Oguntuyo, Jide Kosoko ati Yemi Blaq wa ninu re.

omotola-jalade-sola-koso-shadow-parties-orisun

Osere Omotola Jalade wan i ori set ere naa bayi ni Ibadan, oyo state. Ere naa “Shadow Parties” da le ori ife ati igeyawo laarin agbegbe ati bi oselu pada di ija laarin agbegbe ati oun ijaoloro.
Gbajugbaja olukotan, Yemi Amodu ni o ko itan ere “Shadow parties”

 

saidi-balogun-orisun saidi-balogun-orisun