Skip to content

Simi Fi Akojo Orin ati Aworan Awo Re Titun Han

 

Simi ti fi Akojọ Orin and Aworan Awo Rẹ titun “Omo Charlie Champagne” ti o ma jade ninu osu yi han.

Olorin naa ba olorin Nigeria merin sise ninu Awo yii, Oko re ti a mọ si Adekunle Gold, pelu Maleek Berry, Patoranking ati Ore rẹ Falz.

Awo yii yio jade ni Ojo kokandinlogun osu keta yii, eyi ti o bosi Ojo ibi Simi fun ra ra re.

Wonyi ni Awon Orin ti o wa ninu Awo naa

Charlie
Ayo
Jericho (feat. Patoranking)
By You (feat. Adekunle Gold)
Immortal (feat. Maleek Berry)
Love on Me
The Artist
Move On
Mind Your Bizness (feat. Falz)
Lovin’
Please
I Dun Care
Hide and Seek