Skip to content

SheBaby Setan Lati Gbe Ere Tuntun Ofin Kefa Jade

Shebaby ti o je ogbontarigi osere film ti oruko re n je Seyi Ariyo ti pari ise lori film titun ti akole re n je OFIN KEFA (The 6th Commandment).

E TUN LE KA: Obi O Le Pase Lori Eni Ti Omo Fe Fe, Aye Ti Yato

Ere OFIN KEFA na soro nipa Godliness, Idariji ati Irapada. Eyi ti o je ewo fun arabirin Olamide ninu ere na. Iwa ipanle re je ki o se ese ainidariji ti o je ki o lo si ile ijosin fun idariji ati irapada nibi ti o ti ni ijamba oko ti o je ki o padanu memory re…..SE nkan ti o fe naa ko re ni, Lati pa gbogbo ese re re?   E wo ninu sinima Ofin Kefa ti o feature Damola Olatunji, Bimbo Akinsanya, Shebaby, Aina Gold, Kehinde lawal ati beebelo