Skip to content

Se Orin (Music) Aye Atijo Leko Ninu Ju Ti igbalode lo?

Music (orin) je ounje emi ti o ni ipa lati mu inu eniyan dun, ibaaje hip hop, apala, fuji, sanyan, ewi, juju atibeebeelo. Ni aye ode isnyin awon orin ti a n gbo yato si eyi ti won gbo ni aye atijo. E yi ni atabatubu ati Olori jo n fa lori eto Ojumo Ire… Tani eyin gbe leyin e?

E TUN WO:Se Gbogbo Nkan To N Sele Ninu Ile Wa Lori Ero Ayelujara

E wo ba yii>>>