Opo osere ati awon ti won n ko orin ni won ti gbe igba ibo seyin ri. Awon bi 9ice, Funke Adeshiyan, Desmond Elliot atibeebeelo. Awon kan gbe igba ibo won si yege ti awon kan o si yege. Sugbon se o ye ki awon osere tabi olorin wa yi ki won maa gbe igba ibo nigba idibo…
E TUN LE KA:Nje O Dara Ki Eniyan Fi ISE Ijoba Sile Se ISE ORIN?
Olori Kemi ati Atabatubu yannanna akole oro yi lori eto Ojumo Ire….
E TUN LE WO: