Skip to content

Se O Ro Wipe Oro Buhari ati Nigeria Yii N Fe Adura?

Se o ro wipe oro Buhari ati Nigeria n fe Adura ni ede ti o jade lati enu Ajagun feyinti kan ti o si so wipe se Ori oye ko ni yoo ku si.

Ogagun feyinti naa ti oruko re n je Lawrence Adewusi so wipe ti Aare Mohammadu Buhari ba ku si ori oye, ara Nigeria ko ni gba nnkan ti yoo sele nitori pe Wahal ti yoo rujade ko ni se kekere.

Lehin oro yii, O ke gbajari si Buhari wipe ki o tun iwa re se ki o si so Eto isuna Ile wa di daada nitori pe eni ti o wa lori oye tele ri ko mu inu wa dun. Oun ti a tun ro wipe oun naa yoo se daada naa tun ti n mu inu wa baje ju ti ayeyin wa lo.

Ajagun feyinti naa tun tesiwaju wipe ki Buhari lo so ara re nitori pe ti o ba ku si ori oye ki Saa tie to dopin, Nnkan ti iku re yoo da sile, Agbara enikan ko ni kaa.