Aso Ebi ti di asa kan gboogi ti gbogbo awon eeyan tin se lati aye awon baba wa, iyen aye atijo. Ni ode isin, Mimu Aso Ebi fun Inawo wa o je nkan ti awon yooba nikan nse, awon igbo ati hausa gan o gbeyin ninu mimu Aso Ebi.
Se o pon dandan ki a mu Aso ebi ti a ba fe se Inawo? Kini a gbodo wo ki a to mu Aso Ebi?