Skip to content

Se Gbogbo Nkan To N Sele Ninu Ile Wa Lori Ero Ayelujara

Ni opo igba ni a ma n ri fideo tabi aworan nipa bi igbe aiye awon eyan se n lo lori ero ayelujara. opo igba ni awon eniyan ma n fi gbogbo nkan ti o n sele ninu ile ati igbeyawo won sori ero ayelujara ti o si ti fa ede aiyede laarin ebi ati ara…..

Se o buiyi kun eyan ki eniyan fi gbogbo nkan ti o n sele ninu aiye won bi o ti wun ko kere to si ori ereo aiyelujara?

E TUN LE WO: COMEDY SKIT: E Gbo Eyin Eniyan Tani O Go Ju?

E wo fideo yi ke je ki a mo>>>>>>