Skip to content

Saudi Arabia Gba Alejo Eeyan 1.7m Fun Hajj Odun 2017

Gbogbo eeyan ti o lo fun hajj odun yin i Saudi Arabia ti ku si 1.705m ti o ju oye eeyan 367,095 ti o lo fun ti odun ti o koja. Awon News Agency of Nigeria (NAN) royin wipe iroyin yi kan awon lati owo Directorate General of Passports. Won tun so wipe 1.602million ninu awon alalaji yin i won wa pelu oko ofurufuru ti 87,685 wa pelu moto ati 14,835 wa lati ori omi.

E TUN LE KA: Bi A Se Le Gba Lada Nipa Riran Eniyan Lo Hajj

Oye awon alalaji ti o lo lati Nigeria je 91,000 ti won si so wipe eeyan 51,000 ni won wa lati 22 governmental bodies ti won se hajj ni mecca, medina ati ile mimo miran. Gegebi iroyin ti Saudi so, 16,000 pints of blood ati blood products ni won n gba fun awon alalaji ti won se aisan. Atun rigbo pe bi ile iwosan mesan (9) ni mecca, merin (4) NI Arafat ati merin (4) ni minna ni won ti ko akosegboye ninu ilera jo si..