Nigeria ni ojo isegun (Tuesday) pe omo egbe agbaboolu Arsenal Alex Iwobi pada fun idije agbaboolu to ma wa ye ni osu tonbo fun 2018 world cup qualifier pelu Zambia.
Won yo Alex Iwobi kuro ninu awon ti o gba boolu fun Nigeria nigba ti won gba boolu pelu Cameroon ni osu yi pelu thigh strain sugbon ara re ma ya fun idije boolu ti o ma waye ni uyo ni October 7.
Egbe agbaboolu super eagles wa lori oke group b pelu 10 points ti Zambia ni 7 points ti won si ni 2 rounds of matches lati gba, Ti Nigeria ba yege eyi ri wipe won ma gba boolu pelu Russia ni finals. Ninu Group B naa ni Cameroon wan i ipo keta sugbon ti won ti jaa , Algeria wan i isale pelu 1 point.
Ahmed Musa ti o ti gba boolu fun egbe Leicester ni season yi wa ninu awon ipe iyalenu ti gernot rohr se. Rohr ja goalkeeper dele alampasu sile, eni ti o ti gba boolu fun egbe agbaboolu e Portuguese club, Cesarense
Awon players ti won ma gba boolu fun super eagles against Zambia ni uyo ni oct 7 ni:
Goalkeepers: Daniel Akpeyi (Chippa United/RSA), Ikechukwu Ezenwa (FC Ifeanyi Ubah), Ayodele Ajiboye (Plateau United)
Defenders: William Ekong (Bursaspor/TUR), Abdullahi Shehu (Anorthosis Famagusta/CYP), Leon Balogun (Mainz 05/GER), Elderson Echiejile (Sivasspor FC/TUR), Uche Agbo (Standard Liege/BEL), Chidozie Awaziem (Nantes/FRA), Olaoluwa Aina (Hull City/ENG)
Midfielders: John Mikel Obi (Tianjin Teda/CHN), Ogenyi Onazi (Trabzonspor FC/TUR), Wilfred Ndidi (Leicester City/ENG), Oghenekaro Etebo (CD Feirense/POR), John Ogu (Hapoel Be’er Sheva/ISR), Mikel Agu (Bursaspor/TUR)
Forwards: Ahmed Musa, Kelechi Iheanacho (Leicester City/ENG), Moses Simon (KAA Gent/BEL), Alex Iwobi (Arsenal FC/ENG), Odion Ighalo (Chang Chun-Yatai/CHN), Victor Moses (Chelsea/ENG), Anthony Nwakaeme (Hapoel Be’er Sheva/ISR)