Riyad Mahrez Ni Won Fun Ni Ami Eye Agbaboolu To Dangajiya Ju Ti CAF fun Odun 2016. Nibi Ayeye naa ti GLO se agbekale re lana, ni won ti fun Riyad ni Ami Eye naa nitori wipe Inu didun ni o mu ori ya.
Agbaboolu Leicester City ati ti Ilu Algeria ni won pe ni Agbaboolu ti o peregede julo ni odun ti o koja, ti o si na Saido Mane ati Pierre Emerick Aubameyang ti won jo figa-gbaga nibi Iyanisipo naa.
Mahrez bi won ti n pe ni Ilu re wa lara awon Agbaboolu ti o lowo ti o si lokiki julo ni Leicester city premier league ni akoko ife ti o koja. Won fun ni ami eye ‘PFA Player of the year’ naa lodun naa.
Ninu oro re, a rii gbo wipe “Ko derun rara lati gba iru ami eye naa” o tun tesiwaju wipe “Inu mi dun nitori pe Agbaboolu nnla meji ni mo figa gbaga pelu”