Skip to content

Asorokorin Reminisce Ra oko 2017 Lexus Jeep Fun Ra Re

Asorokorin Remilekun Abdulkalid Safaru ti gbogbo ololufe re mo si reminisce sese ra oko 2017 Lexus SUV jeep fun ra re. Reminisce lo sori eroabnidore instagram re lati so iroyin ayo yi ati aworan oko na nigba ti won gbe oko naa de. Aworan naa fi reminisce han ti o n simi le oko na pelu oti ni egbe e lati fi we oko tuntun naa.

reminisce-orisun

Reminisce je omo Nigeria ti won bi si ipinle Kaduna ti o sig be ni Ogun Sate dagba. Ise Asorinkorin ni ede Yoruba ni gbogbo aye fi moo ti o si je okan ninu awon ti o mo ise asorokorin naa daada

E TUN LE KA: Emi O Ko Orin Bu K cee O – Harrysong