Skip to content

Prime Minista Orile Ede UK Ti So Wipe Ki Won Gbagbe Ofin T’Ode Awon GAY

Prime Minista Orile Ede UK Ti So Wipe Ki Won Gbagbe Ofin T’Ode Awon GAY

Prime Minista ti Orile ede United Kingdom iyen Theresa May ti fun Nigeria ati awon orile ede miran ti o wa ni abe Egbe Commonwealth ni amoran lati gba Igbeyawo Okunrin ati okunrin, beeni ki awon obinrin naa ni agbara lati fe obinrin egbee won.

Arabinrin May so wipe Inu oun baje gidi gaani wipe Orile ede UK gbe ofin ti o de awon ti o n se iru igbeyawo GAY bee lati ile. O so wipe ko ye ki won maa ta iru awon eniyan bee nu nitori ipo ti won ba ara won ni.

Ni Ede geesi o wipe:

“Across the world, discriminatory laws made many years ago, continue to affect the lives of many people  tens of millions of young people. Criminalising same-sex relations and failing to protect women and girls.”

“I am all too aware that these laws were put in place by my own country; they were wrong then and they are wrong now.

“As the UK’s prime minister, I deeply regret that those laws were introduce…as a family, we must respect one another’s cultures and traditions, but we must do so in a manner consistent with equality, as it is clearly stated in the Commonwealth charter.”

Gay-Antigay-uk-us-lesbians