Pataki Imo Itan laye ode oni ni awon ileewe wa. O se pataki lati moo wipe lai s itan, ojo iwaju enikeni yoo ni baibai.
Jide Morounfolu ati Ikeji won joko jiroro lori pataki ede ati asa ati bi imo itan se se pataki si eto eko ni ilu Nigeria.
E wo Fidio yii ki e kogbon,