Skip to content

PATAKI ETO ISINJOBA NYSC NI ILU NIGERIA

Pataki eto isinjoba NYSC ni ilu Nigeria ko se kekere nitori pe, o ti fun awon odo laaye lati keko sii ni ilu ti won ko mo ri.

Jide Morounfolu ati Ikeji won joko jiroro lori pataki ede ati asa ati bi imo itan se se pataki si eto eko ni ilu Nigeria

E wo fidio yii ki e gbo ekunrere bi won ti yananaa Pataki NYSC naa.