Skip to content

Owo Te Odaran Onijibiti Ni Ipinle Eko

Owo Te Odaran Onijibiti Ni Ipinle Eko

Owo palaba segi fun afura si kan to gbi yunju lati lu obirin kan ni jibiti ni abugbo koker ni ifako ijaye ni ipinle Eko.Ara birin na salaye fun awon akoroyin wa. Ewo fanran yi fun ekunrere iroyin na.

YouTube player