Skip to content

Owo Palaba Obinrin Kan Ti Segi Bi O Ti Ju Omotuntun Sinu Salanga

Owo palaba Obinrin kan ni ilu Benue kan ti segi bi awon Agbofinro ti fi seke-seke dee lowo. Won fi esun nla kan wipe o so omo ikoko sinu salanga ni agbegbe Zaki Biam, ni Ijoba Ibile Ukum local government. Eyi sele ni ana ojo aiku osu keta, odun ti a wa yii.
Leyin iforo-wanilenuwo, awon ara adugbo gbo ti omo naa ke, ti o si n pariwo lati inu salanga naa, won si sare fo wo inu salanga naa lati sare gbe omo naa. Won gbe lo si ile iwosan sugbon iya omo naa ti o soo sinu e wa ni Ago-Olopa.
baby obinrin @orisuntv
E TUN LE FIDIO YII: