Skip to content

Owo Palaba Babalawo Awon BADOO Ti Segi Ooo

Owo Palaba Babalawo Awon BADOO Ti Segi Ooo

Ni ilu Nigeria ni a ti gbo wipe owo awon olopa ti te ogbeni kan ti won n pe ni Fatai Adebayo; eyi ti won so wipe o maa n s’oogun fun awon Igara-olosa ati agbenipa Badoo t’on pa omode ati agbalagba ni agbegbe Ikorodu.

Ogbeni Adebayo ti awon ara ilu re mo si Alese bo si owo awon olopa ni idi oosa re ni Ilu IMOSAN ti o wa ni Ijebu-Ode ti ipinle Ogun.

Ileese pepa gbe iroyin naa ni aaro yii gegebi iroyin ti a ri gbo. Atejade inu iwe iroyin naa so wipe Oga olopa CHike Oti ti o je Olukede fun awon olopa ni ilu Eko (Lagos State Police Public Relations Officer -PPRO) ni o mu otito nipa isele naa ja si owo awon Oniroyin.

Awon eniibi badoo ti won ti rimu tele ni won mu awon olopa lo si ilu Imosan lati lo mu Baba-alawo naa.

Awon T’O n Ta Epo Petrol Ti Pariwo Wipe Awon Ko Le Ta Epo Ni 145 MO

Gege bii nnkan ti Awon olopa so, awon omo egbe Badoo naa kii lo pa’niyan lai bere akosejaye enikeni ti won ba fe pa; ti won si maa n s’oogun lati loore ati boore. Iroyin naa tun jade wipe olori awon agbenipa naa fe fese fee/na papa bora, o fe gba ori omi salo sugbon owo tee.

Gege bi won ti so ni ede oyinbo;

Shrine-Fatai-Adebayo-Baddo-Badoo-Killers-ritualists-ritualist-ikorodu-ibeshe-ogun-state-imosan

“Adebayo, 34, who specialises in administering oath on members of the group before they launch any attack, was arrested at his shrine located in Imosan village, a suburb of Ijebu-Ode, Ogun State.

“The arrest of the herbalist followed the arrest of some Badoo cult suspects at the weekend, including the overall head of the group.

“Speaking while parading Adebayo before newsmen at the shrine, the State’s Commissioner of Police, Mr. Imohimi Edgal, said the head of the group was arrested on water during an attempt to escape.

“The CP, who led the operation involving the Commander of Rapid Response Squad, ACP Tunji Disu; Chairman of Lagos State Special Task Force, SP Yinka Egbeyemi, among others, said investigation was still ongoing but that the full details about the arrests made so far would be disclosed on Thursday at a press briefing,” the statement revealed.

Awon olopa wo ile oosa baba-alawo naa bi won ti fiye awon ara-Ikorodu wipe awon yoo mojuto aye ati dukia awon ti o n gbe ilu Ikorodu naa eyi ti o je oro ti awon ti o n gbe agbegbe naa ti n duro de lati enu awon olopa.

Ogbeni Oti tesiwaju ni ede geesi wipe;

Baddo-Badoo-Killers-ritualists-ritualist-ikorodu-ibeshe-ogun-state-imosan

Owo Olopa Te Onisenlaabi Ti O Wa Nidi Ajaale Ilu Sango Ota

“Revealing how the herbalist was arrested, Edgal said, ‘One of the suspects arrested confessed and he led us here that before they go for any killing, the head of the group brings them to this gentleman (Adebayo) to come and carry out oath for both themselves and the piece of stone they used for their killings and that they don’t go for any killing without first of all coming for oath in this shrine and that is why we are here.

“This gentleman is an accomplice before the fact and so definitely we are placing him under arrest and as well as sealing off the shrine till after investigation.

“I will give further details on Thursday during my press briefing but I can assure the good people of Ikorodu, Lagosians and Nigerians that we will not rest until this evil is completely rooted out from Lagos State.

“The CP also made a brief stop-over at the palace of the traditional ruler of Imosan Village, Chief Tajudeen Muili to intimate him of the criminal activities going on in his domain.

“At the shrine located at No 38, Ayegbami Quarters in Imosan, which was later demolished by policemen, there were different charms and big stones said to be used for the illicit activities of the Badoo group,” the police mentioned in addition to an earlier statement.

Ki Isele yii to se, ni ojo keji si oduntuntun ti a wo yii ni a gbo wipe awon Badoo pa idile kan ni agbegbe Ibeshe ni ipinle ogun. Gege bii iwadi wa, Ogbeni Shakiru ni olori idile naa ti won riidaju wipe won pa ki won to kuro nibe. Eyi ko awon olopa l’ominu nitori wipe o tako idaniloju ti awon olopa filele wipe awon yoo bojuto dukia ati emi awon ara ilu.

E WO FIDIO TI O WA LOKE YII KI E LE WO BI O TI SELE. ⇑⇑

Shrine-Fatai-Adebayo-Baddo-Badoo-Killers-ritualists-ritualist-ikorodu-ibeshe-ogun-state-imosan