Olopa orile ede nigeria o se ma ri idi Ajaale ni ilu wa latari wipe gbogbo igba ni owo won n te orisirisi onisenlaibi ti won si n mu won lo si ibi ti ajale won wa. Gbogbo wa ni a ti n gbo nipa Badoo, beeni asi gbo nipa soka ti won ti n sise nla ibi naa. Laipe yii ni awon olopa tun si aso loju eegun ajaale kan ni ilu sango ota…
E TUN LE WO: Didekun Iwokuwo Awon Osere, Ise NFVCB Ni -Femi Adebayo
E wo fidio yii ki e le mo bi o ti n lo>>>>