Skip to content

Owo Epo-Robi Ko Ni Wale Lailai PPPRA

Owo Epo-Robi Ko ni Wale Lailai PPPRA

PPPRA-EPO-ROBI

Awon ajo eto ti o n ris epo-robi PPPRA, ti fi ye awon omo oile-ede Nigeria pe owo epo-robi bentiro ko le le wale lailai wipe ti a ba fe wo bi nkan se n lo, o ye ki owo bntiro gan po ju bi o se wa lo nisin ni.

PPPRA fi eyi se mimo ni igba ti won n da awon ile-igbimo-asofin lohun lori esun ti won fi kan won pe won n fi iya je awon ara ilu nigbaa tita epo-robi ni owon.
Ajo na fi ye wa pe awon ko ni a ma dimu fun owo epi-robi bi bentiro, kerosin at diesel nitori o ni iye ti o ba de lai ibi i won ti ra.
Won salaye lekunrere pe ajo NNPC, MOMAN, NIMASA, ati DAPMA ko sai mo ni igba ti awon gbe owo epo-robi si naira marun-din-logun(N145).

Awon igbimo ti won yan ni ile igbimo asofin lori oro epo-robi ni gbagede ati ipade ti won pe leni i so fun awon ajo PPPRA latui da epo-robi pada si aadorin naira (N70) fun lita kan.
Won se afinhan awon owo perete kookan ti ko ye bi egberun ogorin-le-ni-merin fun gbigbe wole ati egberun ogbon Naira fun awon osise ti won si so wipe awon eleyi je ona eru.

Oga agba PPPRA i ye wa pe gbogbo awon alakoso epo-robi ti joko pero lori fifikun owo ti won n ta betiro.
Ko dara ki PPPRA da gba idalebi lori oro own epo. gbogbo awon ti on se akoso epo-robi lo ye ki won jebi bi epo-obi se gbe owo leri. Nitori gbogbo igba ti a ba joko pero lori oro epo-robi gbogbo wa ni a jo ma n wa nibe. o kan je wipe eto PPPRA ti o man fi to awon ara ilu leti.

O si wipe ti a ba ni ka wo iye ti a na se owo lati dola si naira nisin o ye ki epo-robi won ju bayi lo ti ki ba se ijoba apapo ti dasi. O so wipe iye ti awon se si ni odunrun naira si dola kan sugbon ni isin, dola kan ti je edegbeta-din-ni-meji Naira ti o si je pe awon ti o n ta epo-obi ko ni ase si dola lati Central Bank.

Owo Epo-Robi ko le wale o! a fi ti dola ba wale.