Aderinposonu Alibaba Tun gbe Eto Odoodun Ti January Kale

  alibaba

  Aderinposonu Alibaba Tun gbe Eto Odoodun Ti January Kale

  Gege bi Alibaba ti maa n se lodoodun, Alibaba January 1st. Lati gbe awon aderinposonu bii tie lati mu ori ya ati pa awon eniyan lerin. Opolopo Olorin ni o wa nibe bii, olamide. Tiwa Savage, Niyola ati beebee lo. E wo fidio yii ki e gbo nnkan ti awon eniyan so nipa AliBaba.

  E TUN LE WO FIDIO MIRAN NIBI: E Je Ki Ina Mana-Mana Se Dede Ni Nigeria O, Fashola Lo N Be Buhari O

   

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here