Skip to content

Awon Oluko LAUTECH Ko Lati Pada Si Enu Ise

Awon omo egbe Academic Staff Union of Universities and other workers’ unions ti won wani ile eko giga Ladoke Akintola University of Technology ti so wipe awon o ni pada si enu ise ni oni ojo jimoh (Friday).

Awon Oludari ile eko giga naa so fun awon Oluko, Osise ati akeko ile eko giga naa pe ki won bere ise ni ojo jimoh leyin osu mejo ti won o ti fi sise. Gegebi nkan ti oludar assu so ni LAUTECH, Dr. Biodun Olaniran ati Oludari Joint Action Committee ti LAUTECH, Alhaji Muraina Alesinloye so ni ibi iforowanilenuwo pe ko si nkankan ninu awon osise egbe na ma bere ise nitoripe ko si enikankan ninu won ti o mo nipa oro lati bere ise.

Alaga Asuu tun so siwaju si wipe ajo naa ko mo wipe awon oludari ile eko giga naa ti kede ojo ti won ma bere ise, ti o sit un so wipe oun ranti wipe idi ti won se da ise le ni nitori pe gbogbo nkan ti awon bere lati owo ijoba Ipinle Oyo ati Osun ti siasn owo osu ose mokanla, allowance, gratuity ati pension naa pelu.

“We (ASUU) will not resume until our demands are met. Until our demands are addressed, the strike continues. I am the Chairman of SSANU but I am speaking as the Chairman of JAC now. We are not aware of the resumption and you will agree with me that you cannot obey any directive which you are not aware of.”