Mayorkun-sets-up-a-barbing-salon-for-his-uncle-in-Ilasamaja-Lagos-orisun-tv

Ilumọọka olorin, Mayorkun ti si sọọbu fun ẹgbọn rẹ kan ni ilu eko lati fihan araye wipe oore sise dara gidi gaan ni.

O wipe pẹlu inu didun ni oun fi ṣe eyi si adugbo ibi ti oun ti dagba bẹẹni inu oun dun lati ran ẹnikan lọwọ.

Mayorkun fikun ọrọ rẹ wipe ki ẹnikẹni ti o ba wa ni adugbo Ilasamaja tabi agbegbe naa, ki wọn lọ sibẹ lọ gẹrun.

Gbogbo wa ni a mọ wipe ọmọ ologo naa ti ṣee daadaa fun ara rẹ lati igba ti DAVIDO ti gba orukọ rẹ wọle si abẹ asia ẹgbẹ olorin DMW.

Ki ọba oke maa bu si apo rẹ ni oooo …MB’Amin.

mayorkun

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here