Alex-Chamberlain-orisun

Egbe agbaboolu Liverpool ti gbimopo pelu egbe agbaboolu arsenal lati ra alex oxlade chamberlain fun oye owo £40m. Egbe agbaboolu ti won wo pupa je aayo lati ra midfielder yi leyin ti o ko lati lo si egbe iko Chelsea nitori idi ti oun nikan mo npa.

E TUN LE KA: Wayne Rooney Feyinti Ni Idi Gbigba Boolu Fun England

Oxlade-Chamberlain wani igbeyin ifowobowe pelu egbe agbaboolu gunners ti won si n reti pe yoo pari ifowoluiwe re si anfield lai pe.

 

Awon asoju Chamberlain, Colossal Sport Management naa fi iroyin yi si ori ero abanidore (twitter) won ki won to yoo danu… wo ko wipe… ‘DEAL AGREED!!!! # LIVERPOOL # YNWA # COLOSSAL # LFC’.

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here