Osere iyabo ojo ti se tan lati tan eka ile ise re siwaju si. Iyabo Ojo ti o je alase ati oludasile iyara Oge (beauty salon) ti se tan lati si ile ounje igbalode ti won ti n ta Amala si lekki, lagos.

iyabo-ojo-abula-spot-catering-services

Iroyin ayo yi di mimo nigbati osere opeyemi aiyeola fi oro yi si ori ero abanidore instagram re ti iyabo ojo si so ojo ti oun yoo sii ile ounje naa…

opeyemi-aiyeola-orisun iyabo-ojo-lounge-lekki-lagos-orisun

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here