Evans So Wipe Ohun J’ebi Esun Gbomo-Gbomo Ni Ile Ejo

evans-kidnapper-court-orisun

Gbaju-Gbaja gbomo-gbomo, Chukwudumeme Onwuamadike, ti gbogbo eniyan mo si Evans, bebe wipe ohun j’ebi esun ote ati gbomo-gbomo. O si ti lo ba oju ile-ejo giga ti Ikeja ni ilu Eko ni owuro yii. Ohun ati awon marun miran ni won fi esun ote ati gbomo-gbomo kan.

E TUN LE KA: Ile Ejo Gba Nkan Ini To To $16.4m Lowo Diezani

Adajo naa si pase wipe ki gbogbo awon okunrin ti a fi esun kan ki won si wa ni kirikiri nigbati awon obinrin ti won so wipe awon ko jebi esun ti a fi kan won, ki won wa ni kirikiri ti obinrin.

 

Won si sun ejo naa si ojo kokandinlogun osu kewa.

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here