Skip to content

Ẹ Wo Nnkan Ti Awọn ẸṢỌ Ẹnu Ọna House Of Assembly Ati Oṣiṣẹ Ibẹ Ṣe Si Ile Naa

Ẹ Wo Nnkan Ti Awọn ẸṢỌ Ẹnu Ọna House Of Assembly Ati Oṣiṣẹ Ibẹ Ṣe Si Ile Naa

Awọn ẹṣọ ati oṣiṣẹ ile igbimọ aṣofin agba ni wọn duro si iwaju ile igbimọ aṣofin lẹyin iyanṣẹ lodi ti o ṣẹlẹ ni ọjọ Aje ọjọ ‘ketadinlogun ọdun yii lati ja fun ẹtọ wọn lori bi iṣẹ wọn ṣe n lọ.
Ni bii aago mẹwa-abọ aarọ, wọn ko ri asọfin kankan ni agbegbe naa leyin ti wọn ti pinnu wipe awọn ko ni gba ẹnikan kan laaye lati wọ abawọle Ile-igbimọ aṣofin tabi Ile Arẹ orilẹ ede (Presidential Villa)

Gẹgẹ bi a ti rii gba lati ọwọ ileeṣẹ ti o n kọ iroyin: Daily Trust sọ wipe Akọwe ile-aṣofin naa Mohammed Sani-Omolori tẹ iwe jade ni aarọ ọjọ iṣẹgun wipe awọn adari ile-igbimọ aṣofin naa ti ran awọn ọlọpa ati ajọ DSS lati mu gbogbo awọn ti o ba ru ofin bẹẹni ki wọn si fi idi ofin mulẹ ni gbogbo agbegbe naa ki ẹmi ati ohun-ini le wa ni pipe ki awọn ẹgbẹ Aṣofin ilẹ wa naa le ṣe awọn iṣẹ ti o yẹ ki wọn ṣe lai si idiwọ kan tabi omiran.
Gẹgẹ bi o ti sọ lai yọ ohun kan kuro nibẹ ni ede gẹẹsi, O wipe;

“The leadership of the National Assembly called the meeting because they know that almost all the issues raised by the striking workers were being addressed by the management. It was unanimously agreed that the management had made sufficient plans and efforts to address all the grievances of the workers and ensure their happiness.
“We were sure that the issues raised by the workers have been well attended to and that it is necessary for the business of the National Assembly to continue without any disturbance. Both chambers must hold their normal plenary tomorrow morning to prepare the ground for the visit of President Muhammadu Buhari on Wednesday, December 19, 2018 to present the budget proposal to the joint sitting of the Senate and the House of Representatives.

“We have therefore mandated the security agencies to perform their duty of maintaining law and order in the National Assembly Complex and its surrounding. They must enforce the laws which allow the striking workers to down tools if they choose to and also the ones which restrain them from disturbing those who choose to work or stop parliamentarians from entering the chambers or their offices to do the work for which they were elected.

“Senators and members of the House of Representatives, their aides, other workers and people who have legitimate business within the National Assembly Complex are therefore advised to come in as they will be free to operate without any hinderance and molestation.

“If President Buhari is unable to present the budget proposal on Wednesday as scheduled Nigerians, should hold the security agencies responsible for failing in the performance of their duties”, the leadership of the federal legislature stated.