Muhamadu Buhari
Muhamadu Buhari

BUHARI SE OJO IBI ODUN KERIN FUN ZEE

Aare orile ede Naijiria, Muhamadu Buhari pelu aya re se ajoyo ayeye ojo ibi kerin fun okan ninu omo-omo won. Oruko omo naa ni Zee.

E o ranti wipe ariyanjiyan kan waye laarin Aare  ati Iyawo re, Aisha ni bi osu meji seyin lori ipa ti aare so wipe o n ko ninu ile ohun. A ni gbagbo pe won ti yanju aawo naa.

E TUN KA ELEYI:    Oyedepo’s Miracle Described As Fake

A ki Aare ati gbogbo Molebi re, paapaa julo Omode’binrin Zee fun ayeye ojo ibi yi.

Aseyi samodun o.!

 

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here