Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun
#IroyinLoriOrisun Davido fi esi si iroyin nipa fifi owo ofun muu ati wipe nnkan ti o so niyiiNi ijakeji awon iroyin oniruuru ti o n lo lori iku Tagbo Umeike, Davido ti won ti mu fi esi si iroyin naa. Oga olopa naa pe gbaju-gbaja olorin naa ni igba ikeji ni eni pelu awon ore re, ti win pada ti won mo atimole leyin ti iwadi fihan pe oku iku asphyxiation (didi eniyan ni ona ti o n gba mi), ti awon ore re si so wipe oti amupara ti o mu lo paa. E ranti, Caroline Danjuma fi esun kan Davido ati awon elegbe re nipa jiju oku Tagbo sile ni ile-iwosan gbogbogboo (general hospital) ni Ilu-Eko ti won si salo. Davido ti o sese de ni bii wakati die seyin so awon nkankan. Ki e le mo awon nnkan ti Davido so, e wo awon multiple pictures ti a post si oke. E tun le kan siwa lori ero ayelujara wa ni WWW.ORISUN.TV#OrisunTv #Orisun #Entertainment #Entertaining #IroyinLoriOrisun #Iroyin #News #Murder #Death

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun

Davido ti se afihan wipe oun ko ni ikun sinu kankan si enikeni ti o ro wipe oun ni owo ninu iku Tagbo.
Osere ‘binrin Caroline Danjuma ti o fi esun kan wipe o ni owo ninu iku Tagbo ti o si rii pe o lo si ago olopa, Davido ti won ti tu sile ti jade lati so wipe oun ti dariji awon ti o ni owo ninu iku ore oun ti o di oloogbe.

E tunle ka: Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re

Davido koo si ori ero ayelujara snapchat wipe:

“Thank you Jesus” before calling out “persons that said false things about me or accused me of what I don’t know.

“I sincerely forgive you.. and God bless you. We move on. Let’s all be better. Thank you Lord.”

“Thank you to everyone that prayed for me and to those who didn’t.. Maybe you forgot,” he wrote.

“We thank God all in all. Now lets get back to the music.”

 

 

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here