Skip to content

E Wo Nnkan Ti Osinbajo So Lati Fi Tako BUHARI #LazyNigerianYouth

E Wo Nnkan Ti Osinbajo So Lati Fi Tako BUHARI #LazyNigerianYouth

Igbakeji Are orile-ede Nigeria, Ogbeni Yemi Osinbajo ti gbe osuba-kare fun awon odo ilu Nigeria pelu awon oro ti o so lodi si #LazyNigerianYouth; wipe awon odo ile wa ya Ole-alaininnkan se.

Ni ibi ipade kan ni Covenant Church Iganmu ni ilu Eko ni Osinbajo ti pe fun isokan laarin egbeegbe, awon oloselu, eya-meya, ede kan si omiran, okunrin ati obinrin pelu Omode, odo ati agbalagba fun itesiwaju ilu Eko ati orile ede Nigeria lapapo.

Idagbasoke gege bi o ti tumo si je ohun ti a le f’oju si ati oun ti a le fi ise se nipa bi awon olori iselu se n gb’iyanju lati tun orile ede se, tun odede se, tun eto eko pelu ilera ara awon eniyan lai gbagbe esin.

IJOBA Buhari Ti Pofo Leyin Gbogbo Ileri Ti O Ti Se – Bishop Oyedepo

Okunrin ati obinrin ti o n se owo, ti o n se ise agbe, ti o mo nipa eto eko tabi awon ti o n se ise owo nipa sise ise karakara;tokan-tokan je okunfa fun igbesoke/idagbasoke orile ede, beeni won n fikun eto oro-aje/isuna orile ede.

 

Ni ede oyinbo, o wipe:

This afternoon I will share some of the stories of young people many of whom I have met who by just doing their own work faithfully have contributed to  building our economy, increased our national pride and confidence, created opportunities for others, as well as, inspired others to be the best they can be.

Yemi-Osinbajo-buhari-lazy-youth