Skip to content

Osere Iyabo Ojo Si Ile Ounje Re (photos)

Osere Iyabo Ojo ti sii ile ounje ti won ti n ta amala si lekki, lagos state; Ayeye isile naa waye ni opin ose yii… Osere Iyabo Ojo o sii ile ounje nikan , o tun sii ile oti naa si lekki.

Opo ore ati ebi ni won wa nibi isile naa, awon eeyan bi  Deaconess Omolewa AHMED… Executive First Lady of Kwara state, fathia balogun ati omo iyabo ojo naa…. Iyabo Ojo bo si ori ero abanidore instgram lati fi idunnu re han, o ko wipe….“It was indeed a grand opening yesterday & its all because u came through for Us,Thank you ?????? for making Fespris Limited Opening a success: Abula Spot, Fespris Lounge & Bar, Fespris Spa, Fespris Nail Studio, Fespris-makeup Studio, Fespris Beauty Product, Fespris Boutique, Fesprisproduction, Fespris Event Management. 
We have come to stay & service is our passion: Pls feel free to call on us or visit us for any of the services we render,
we also provide Home service for Fesprisworld & delivery for our Abula Spot.
…… We promise to make u proud”

iyabo-ojo-orisun

iyabo-ojo-orisun

iyabo-ojo-orisun

iyabo-ojo-orisuniyabo-ojo-orisun

iyabo-ojo-orisun

Tags: