Osere Eniola Badmus wo iya ija pelu ore re timo timo Sophia momodu ti o je iya omo davido lenu ijometa; sugbon lowo yi ojo wipe Eniola Badmus ti roo daadaa, o siti pinu lati se agba ki o pari ija ti o wa laarin awon mejeeji.
E TUN LE KA: Osere Eniola Badmus Na Idaji Million Naira Fun Aseje Ojo Ibi Re
Eniola bo si ori ero abanidore snapchat re lati fi atejise naa ranse, o ni ‘Go and Sin no More’, o sir anti gbogbo awon nkan meremere ti awon mejeeji ti jo se po. O sit un ko wipe oun feran davido ,oun si feran nkan tabi enikeni ti o ba je mo davido….