Osere Bimbo Thomas je osere kan gboogi ninu awon osere ti n se ere agbelewo ni yoruba, iyen yoruba movie industry, loni osere Bimbo Thomas se ojo ibi re loni September 29th, 2017, looto a o mo oye omo odun ti osere naa pe sugbon a ki won ku ojo ibi… Bimbo Thomas ko ai ori ero abanidore instagram re pe;
Lai pe yi, ni osu to koja ni omo osere bimbo thomas iyen jayden naa se ojo ibi re ti osere naa fi aworan orisirisi si ori ero abanidore instagram re…