Skip to content

Osere Bimbo Thomas Fi Aworan Omo Re Yangan

Osere Bimbo Thomas ti a mo si Bursty ninu ere jenifa fi opolopo aworan omo re jayden han lori ero abanidore instagram. Omo Bimbo thomas, jayden pe omo odun kan ni aipe yi ti won si se ni alarinrin. Ni ori eroabanidore instagran na, Bimbo ko si ibe wipe>>> “My MCW, if there is sumffin like dah, will celebrate you all day baby jay”

E TUN LE KA: Odunlade Adekola Ko ni Baba Omo Mi- Bukola Adeeyo

BIMBO-THOMAS-SON-JAYDEN-ORISUN

BIMBO-THOMAS-SON-JAYDEN-ORISUNBIMBO-THOMAS-SON-JAYDEN-ORISUNBIMBO-THOMAS-SON-JAYDEN-ORISUN