Skip to content

#Orisun: IDI TI MO SE MU MUSULUMI BII IGBAKEJI TI A JO FE DIJE IBO ODUN 2019 – EL RUFAI

#Orisun: IDI TI MO SE MU MUSULUMI BII IGBAKEJI TI A JO FE DIJE IBO ODUN 2019 – EL RUFAI

Gomina ipinle Kaduna, Mallam nasir El-Rufai ti gba oro buruku leyin ti o so wipe Musulumi ni oun yoo fi se igbakeji nibi ibo odun 2019 ti o n bo.

Awon eniyan bere sii so wipe nnkan ti ko dara ni igbese naa; wipe ko le je musulumi ki igbakeji re naa je musulumi.

Won so wipe; pelu gbogbo nnkan ti o n sele ni ipinle naa, wahala ni yoo je fun awon eniyan beeni yanponyanrin yoo be sile ti musulumi ati musulumi ba wole-ibo.

Ni igba ti Nasir el Rufai soro, o so wipe idi ti oun fi da iru aba bee ye oun gidi gaan; eyi ti o so ni igba ti awon eniyan lati ijoba-ibile sanga ni ipinle naa wa kii fun mimu Dokita Balarabe gege bii igbakeji re.

Gege bi Gomina naa ti so, iwe pelebe ti won ko oruko naa si ni bii oruko mejilelogbon ti won si ja wa si iye eniyan mejila, ko pe re ni won jaa si marun-un.

El Rufai so wipe atileyin Buhari wa lara awon nnkan ti o je ki oun mu eni ti oun mu lai ro esin ti o n se.

Ni ede geesi o wipe:

“The president then told me that since I have included women in the list I should give them priority and that was how we arrived at Dr. Balarabe.
“But the president also asked me how old she was and I said I did not know because among the documents I had her age was not there.
“The president then said he hopes Dr. Balarabe is neither a Fulani nor Hausa like me and I said I do not know her ethnic group but I told him she’s related to one of his aides, Alhaji Maikano, then he said if that is the case then she’s Numana.”
The governor noted also that, the other part was getting the number of Dr Balarabe, whom many described as a good choice for the position.
“When I called her she said she was in Kenya, I told her I just came out of the president’s office and he has affirmed that you should be my running mate in the 2019 elections and I asked her whether she accepts.
“She did not give an answer immediately but she called me back after some minutes and said she’d accepted.”