Skip to content

#OrinTitun: ZLATAN (@zlatan_ibile) – ZANKU : LEGWORK

ZLATAN – ZANKU : LEGWORK

#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe)

Ọgbẹni Olorin ti aye n sọ lọwọ-lọwọ; ZLATAN Ibile ti gbe fidio orin rẹ ZANKU jade pẹlu ara ọtọ. Lẹyin ti Orin naa ti gba gbogbo adugbo, Ilumọọka naa gbe fidio rẹ jade pẹlu ijo ZANKU. Pokolee, Rahmon jago ati awọn ilumọọka ori afẹfẹ naa ko gbẹyin ninu fidio naa.

#MilikiEXPRESS: IYATỌ TI O WA LAARIN ẸNI T’O KỌ IṢẸ THEATRE LABẸ ENIYAN ATI TI O LỌ ILEEWE

Ẹ wo fidio yẹn l’oke ki ẹ si f’esi si nnkan ti ẹ ro nipa orin naa: