TENI – UYO MEYO
Tẹni ni Olorin ti aye n fẹ ni asiko yii; oun ni ọmọ ti wọn sọ lọwọ-lọwọ. O ti gbe fidio miran jade bayii pẹlu awọn aworan lati igba ti o ti bẹrẹ orin kikọ titi o fi di ilumọọka.
Uyo Meyo jẹ orin ti awọn eniyan maa n kọ ti Tẹni ba ti n kọrin. Eyi ni o bi gbigbe fidio orin naa si ori igba fun awọn ololufẹ Teni.
Ẹ wo fidio naa nibi: