Seyi Shay ti fi fidio Orin rẹ ti akole rẹ jẹ Gimme Love bẹrẹ Odun Titun yi.
#OrinTitun: TENI (@tenientertainer) – UYO MEYO
Fidio orin titun naa ti oun ati ilumọka olorin ti a mọ si Runtown jo kọ papo ni o fi bi ewa Olorin naa ti ri.
Clarence Peters ni o dari fidio yi.
#OrinTitun: Harrysong – Journey (Irin Ajo)
Ẹwo fidio yi Ki Ẹ jẹ ki a mọ bi ẹ ti fẹra rẹ to