Skip to content

#OrinTitun: Falz – Talk

Ogbeni FALZ ti gbe orin titun jade labe asia Bahdguy records. Orin titun yii je orin ti o yoo da igboro ru nitori wipe o ko orin naa lati fi pe awon Oselu Nigeria lejo beeni o fi orin naa fun ipe fun atunse lori awon wahala ti won ko b’ojuto.

Fidio naa jade pelu isere geemu bi awon oselu se n fi wa ta tete beeni o se afihan awon nnkan ti ijoba ko ko’bi ara si.

E wo fidio naa ni’sale ki e si f’esi si nnkan ti e ro:

YouTube player